Edit Lyric - Lyricshot
Feature Note:
After successfully editing the lyric, we will review your submission. The review process may take up to one week.
Current Song
Fuji Interlude
Seyi Vibez
Your Name
*
Lyric Content
*
Mo kira fun Ọba Ilayi Tí o dójú ti mí o Ko si ẹni t'omọ la t'ọwọ kọ Emí náà á d'eyan o Ẹlẹda mi má jẹ n rá maye Ehhh, mo ti dé bí mo ṣe ń dé o Mo tún tún gbé ere mí dé o Oluwaloseyi o Ẹni fẹ ná mí owó o kó wa bí Bisi Bisi, níwoyii? (Níwoyii?) Sexy mama, ni ma yi (Ni ma yi) Ṣé o má lo mọ singer yii (Singer yii) Everyday ká ní bayii (Ní bayii) Àwọn kàn ti kọ ṣiwaju, wọn tún kọ'rin ni sinyin o Àwọn kan wa pọ níwájú, Alabi o wesẹ mí o Bá mi kí bàbá Balo Ẹni jẹun lo ma yo Ki'ku ma pa brother mi o Ki'kú má pa maga mi o K'emi r'owó ṣayé Wọn gbọ mi ní Germany dé'Ibafo Ko mọ'gba t'owo ku wazo o Àwọn girl ti wọ Palazzo O ya, baby mi wa jo O ti mọ p'owo dẹ kún'lé o 50 Million ku ẹ wazo Money dey see my car o Loseyi, Labaika o Àwọn kan fẹ gara ní massion o When I say o ya o ya, let's dance O ya o ya, jẹ ká jo O ya o ya, let us dance Jẹ ka lọ s'agbo Loseyi o O ya o ya, let's dance O ya o ya, jẹ ka jo O ya o ya, let us dance Jẹ ka lọ s'agbo Loseyi o O ya o ya, let's dance O ya o ya, jẹ ka jo O ya o ya, let us dance Jẹ ka lọ s'agbo Loseyi o O ya o ya, let's dance O ya o ya, jẹ ka jo O ya o ya, let us dance Jẹ ka lọ s'agbo Loseyi o
Minimum 10 characters required
Submit Lyric Edit
Return to Lyric Page