Home / Seyi Vibez / Fuji Interlude
Fuji Interlude by Seyi Vibez
Worldwide

Fuji Interlude

by Seyi Vibez

Release Date: 2023-06-08

Lyrics

Mo kira fun Ọba Ilayi
Tí o dójú ti mí o
Ko si ẹni t'omọ la t'ọwọ kọ
Emí náà á d'eyan o
Ẹlẹda mi má jẹ n rá maye
Ehhh, mo ti dé bí mo ṣe ń dé o
Mo tún tún gbé ere mí dé o
Oluwaloseyi o
Ẹni fẹ ná mí owó o kó wa bí
Bisi Bisi, níwoyii? (Níwoyii?)
Sexy mama, ni ma yi (Ni ma yi)
Ṣé o má lo mọ singer yii (Singer yii)
Everyday ká ní bayii (Ní bayii)
Àwọn kàn ti kọ ṣiwaju, wọn tún kọ'rin ni sinyin o
Àwọn kan wa pọ níwájú, Alabi o wesẹ mí o
Bá mi kí bàbá Balo
Ẹni jẹun lo ma yo
Ki'ku ma pa brother mi o
Ki'kú má pa maga mi o
K'emi r'owó ṣayé
Wọn gbọ mi ní Germany dé'Ibafo
Ko mọ'gba t'owo ku wazo o
Àwọn girl ti wọ Palazzo
O ya, baby mi wa jo
O ti mọ p'owo dẹ kún'lé o
50 Million ku ẹ wazo
Money dey see my car o
Loseyi, Labaika o
Àwọn kan fẹ gara ní massion o
When I say o ya o ya, let's dance
O ya o ya, jẹ ká jo
O ya o ya, let us dance
Jẹ ka lọ s'agbo Loseyi o
O ya o ya, let's dance
O ya o ya, jẹ ka jo
O ya o ya, let us dance
Jẹ ka lọ s'agbo Loseyi o
O ya o ya, let's dance
O ya o ya, jẹ ka jo
O ya o ya, let us dance
Jẹ ka lọ s'agbo Loseyi o
O ya o ya, let's dance
O ya o ya, jẹ ka jo
O ya o ya, let us dance
Jẹ ka lọ s'agbo Loseyi o